- 
	                        
            
            Léfítíkù 22:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        8 Bákan náà, kò gbọ́dọ̀ jẹ òkú ẹran èyíkéyìí tàbí ohunkóhun tí ẹranko burúkú fà ya, kó sì di aláìmọ́ nípasẹ̀ rẹ̀.+ Èmi ni Jèhófà. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Ìsíkíẹ́lì 44:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        31 Àwọn àlùfáà kò gbọ́dọ̀ jẹ ẹyẹ tàbí ẹran kankan tó ti kú tàbí èyí tí ẹranko fà ya.’+ 
 
-