-
Léfítíkù 11:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “‘Nínú àwọn ẹ̀dá abìyẹ́ tó ń gbá yìn-ìn, tó ń fi ẹsẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin rìn, àwọn tó ní tete lókè ẹsẹ̀ wọn láti máa fi tọ lórí ilẹ̀ nìkan ni ẹ lè jẹ.
-