ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 6:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Màá mú yín bí èèyàn mi, màá sì di Ọlọ́run yín.+ Ó dájú pé ẹ ó mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín tó mú yín kúrò lábẹ́ àjàgà àwọn ará Íjíbítì.

  • Ẹ́kísódù 29:46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 Ó sì dájú pé wọ́n á mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run wọn, tó mú wọn kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì kí n lè máa gbé láàárín wọn.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run wọn.

  • Hósíà 11:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 “Nígbà tí Ísírẹ́lì wà ní ọmọdé, mo nífẹ̀ẹ́ rẹ̀,+

      Láti Íjíbítì ni mo sì ti pe ọmọkùnrin mi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́