-
Léfítíkù 13:24, 25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 “Tàbí tí iná bá jó ẹnì kan, tó sì dápàá sí i lára, tí àbààwọ́n tó pọ́n tàbí tó funfun sì wá yọ lójú àpá náà, 25 kí àlùfáà yẹ̀ ẹ́ wò. Tí irun tó wà lójú àbààwọ́n náà bá ti funfun, tó sì rí i pé ó ti jẹ wọnú kọjá awọ, ẹ̀tẹ̀ ló yọ jáde lójú àpá yẹn, kí àlúfáà kéde pé ẹni náà jẹ́ aláìmọ́. Àrùn ẹ̀tẹ̀ ni.
-