Léfítíkù 14:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kí àlùfáà mú ọmọ àgbò kan, kó fi rú ẹbọ ẹ̀bi+ pẹ̀lú òróró òṣùwọ̀n lọ́ọ̀gì náà, kó sì fì wọ́n síwá-sẹ́yìn bí ọrẹ fífì níwájú Jèhófà.+
12 Kí àlùfáà mú ọmọ àgbò kan, kó fi rú ẹbọ ẹ̀bi+ pẹ̀lú òróró òṣùwọ̀n lọ́ọ̀gì náà, kó sì fì wọ́n síwá-sẹ́yìn bí ọrẹ fífì níwájú Jèhófà.+