-
Léfítíkù 14:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Kí àlùfáà wá mú lára ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ẹ̀bi, kó sì fi sí ìsàlẹ̀ etí ọ̀tún ẹni náà tó fẹ́ wẹ ara rẹ̀ mọ́ àti àtàǹpàkò ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ àti àtàǹpàkò ẹsẹ̀ ọ̀tún rẹ̀.
-