Léfítíkù 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “‘Àmọ́ tí agbára rẹ̀ ò bá gbé àgùntàn, kó mú ẹyẹ oriri méjì tàbí ọmọ ẹyẹlé méjì+ wá fún Jèhófà láti fi rú ẹbọ ẹ̀bi fún ẹ̀ṣẹ̀ tó dá, ọ̀kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, ìkejì fún ẹbọ sísun.+
7 “‘Àmọ́ tí agbára rẹ̀ ò bá gbé àgùntàn, kó mú ẹyẹ oriri méjì tàbí ọmọ ẹyẹlé méjì+ wá fún Jèhófà láti fi rú ẹbọ ẹ̀bi fún ẹ̀ṣẹ̀ tó dá, ọ̀kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, ìkejì fún ẹbọ sísun.+