Léfítíkù 14:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kí àlùfáà sun ẹran ẹbọ sísun àti ọrẹ ọkà+ lórí pẹpẹ, kí àlùfáà sì ṣe ètùtù fún un,+ yóò sì di mímọ́.+
20 Kí àlùfáà sun ẹran ẹbọ sísun àti ọrẹ ọkà+ lórí pẹpẹ, kí àlùfáà sì ṣe ètùtù fún un,+ yóò sì di mímọ́.+