- 
	                        
            
            Léfítíkù 14:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        41 Kó wá mú kí wọ́n ha inú ilé náà dáadáa, kí wọ́n sì da ohun tí wọ́n fi rẹ́ ilé àti àpòrọ́ tí wọ́n ha lára rẹ̀ sí ẹ̀yìn ìlú níbi àìmọ́. 
 
-