-
Léfítíkù 12:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 “‘Tí ọmọ tó bí bá jẹ́ obìnrin, ọjọ́ mẹ́rìnlá (14) ni kó fi jẹ́ aláìmọ́, bó ṣe máa ń jẹ́ aláìmọ́ tó bá ń ṣe nǹkan oṣù. Kó máa wẹ ẹ̀jẹ̀ kúrò lára rẹ̀ fún ọjọ́ mẹ́rìndínláàádọ́rin (66) tó tẹ̀ lé e.
-