- 
	                        
            
            Léfítíkù 4:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        8 “‘Lẹ́yìn náà, kó yọ gbogbo ọ̀rá tó wà lára akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ náà, títí kan ọ̀rá tó bo ìfun àti ọ̀rá tó yí ìfun ká 9 àti kíndìnrín méjèèjì pẹ̀lú ọ̀rá tó wà lára wọn nítòsí abẹ́nú. Kó yọ àmọ́ tó wà lára ẹ̀dọ̀, pẹ̀lú àwọn kíndìnrín+ rẹ̀. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Léfítíkù 9:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        10 Ó mú kí ọ̀rá àti àwọn kíndìnrín àti àmọ́ tó wà lára ẹ̀dọ̀ látinú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ náà rú èéfín lórí pẹpẹ, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.+ 
 
-