-
Léfítíkù 15:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ẹnikẹ́ni tó bá fara kan ohunkóhun tí onítọ̀hún jókòó lé yóò jẹ́ aláìmọ́ títí di alẹ́, kí ẹnikẹ́ni tó bá sì gbé àwọn nǹkan yẹn fọ aṣọ rẹ̀, kó fi omi wẹ̀, kó sì jẹ́ aláìmọ́ títí di alẹ́.
-