Léfítíkù 4:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Kó yọ gbogbo ọ̀rá+ rẹ̀, bó ṣe yọ ọ̀rá kúrò lára ẹran ẹbọ ìrẹ́pọ̀,+ kí àlùfáà sì mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ láti mú òórùn dídùn* jáde sí Jèhófà; kí àlùfáà ṣe ètùtù fún un, yóò sì rí ìdáríjì.
31 Kó yọ gbogbo ọ̀rá+ rẹ̀, bó ṣe yọ ọ̀rá kúrò lára ẹran ẹbọ ìrẹ́pọ̀,+ kí àlùfáà sì mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ láti mú òórùn dídùn* jáde sí Jèhófà; kí àlùfáà ṣe ètùtù fún un, yóò sì rí ìdáríjì.