- 
	                        
            
            Léfítíkù 12:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        7 Kí àlùfáà mú un wá síwájú Jèhófà, kó ṣe ètùtù fún obìnrin náà, á sì mọ́ kúrò nínú ẹ̀jẹ̀ tó ń dà lára rẹ̀. Èyí ni òfin nípa obìnrin tó bímọ ọkùnrin tàbí obìnrin. 
 
-