Hébérù 9:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Torí náà, ó pọn dandan pé ká wẹ àwọn ohun tó ṣàpẹẹrẹ+ àwọn ohun ti ọ̀run mọ́ láwọn ọ̀nà yìí,+ àmọ́ àwọn ẹbọ tó dáa ju èyí lọ fíìfíì ló yẹ àwọn ohun ti ọ̀run.
23 Torí náà, ó pọn dandan pé ká wẹ àwọn ohun tó ṣàpẹẹrẹ+ àwọn ohun ti ọ̀run mọ́ láwọn ọ̀nà yìí,+ àmọ́ àwọn ẹbọ tó dáa ju èyí lọ fíìfíì ló yẹ àwọn ohun ti ọ̀run.