-
Títù 2:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 bí a ti ń dúró de àwọn ohun aláyọ̀ tí à ń retí+ àti bí Ọlọ́run Olódùmarè ṣe máa fara hàn nínú ògo pẹ̀lú Olùgbàlà wa, Jésù Kristi, 14 ẹni tó yọ̀ǹda ara rẹ̀ nítorí wa+ kó lè tú wa sílẹ̀*+ kúrò nínú gbogbo onírúurú ìwà tí kò bófin mu, kó sì wẹ àwọn èèyàn rẹ̀ mọ́, àwọn ohun ìní rẹ̀ pàtàkì, tí wọ́n ní ìtara fún iṣẹ́ rere.+
-
-
1 Jòhánù 1:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Àmọ́, tí a bá ń rìn nínú ìmọ́lẹ̀ bí òun fúnra rẹ̀ ṣe wà nínú ìmọ́lẹ̀, a ní àjọṣe pẹ̀lú ara wa, ẹ̀jẹ̀ Jésù Ọmọ rẹ̀ sì ń wẹ̀ wá mọ́ kúrò nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀.+
-