-
Hébérù 9:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Torí tí ẹ̀jẹ̀ àwọn ewúrẹ́ àti ti àwọn akọ màlúù+ àti eérú ọmọ màlúù* tí wọ́n fi wọ́n àwọn tó ti di aláìmọ́ bá sọ wọ́n di mímọ́ kó lè wẹ ẹran ara mọ́,+ 14 ǹjẹ́ ẹ̀jẹ̀ Kristi,+ ẹni tó tipasẹ̀ ẹ̀mí àìnípẹ̀kun fi ara rẹ̀ rúbọ sí Ọlọ́run láìní àbààwọ́n kò ní ṣe jù bẹ́ẹ̀ lọ láti wẹ ẹ̀rí ọkàn wa mọ́ kúrò nínú àwọn òkú iṣẹ́,+ ká lè máa ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ fún Ọlọ́run alààyè?+
-
-
Hébérù 10:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Tí kò bá rí bẹ́ẹ̀, ṣé wọn ò ti ní dáwọ́ rírú àwọn ẹbọ náà dúró? Torí tí a bá ti wẹ àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ mọ́ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo, wọn ò ní mọ̀ ọ́n lára pé àwọn jẹ́ ẹlẹ́ṣẹ̀ mọ́.
-