-
Léfítíkù 8:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Mósè pa á, ó fi ìka rẹ̀ mú ẹ̀jẹ̀ ẹran náà,+ ó fi sára àwọn ìwo tó wà ní gbogbo ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ, ó sì wẹ ẹ̀ṣẹ̀ kúrò lára pẹpẹ náà, àmọ́ ó da ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ, kó lè yà á sí mímọ́ láti ṣe ètùtù lórí rẹ̀.
-
-
Léfítíkù 16:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Kó wá jáde wá síbi pẹpẹ+ tó wà níwájú Jèhófà, kó ṣe ètùtù fún un, kó sì mú lára ẹ̀jẹ̀ akọ màlúù náà àti lára ẹ̀jẹ̀ ewúrẹ́ náà, kó wá fi sára àwọn ìwo tó wà ní gbogbo ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ.
-