Diutarónómì 12:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ṣáà ti pinnu pé o ò ní jẹ ẹ̀jẹ̀,+ má sì yẹ ìpinnu rẹ, torí pé ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí,*+ o ò sì gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀mí* pọ̀ mọ́ ẹran.
23 Ṣáà ti pinnu pé o ò ní jẹ ẹ̀jẹ̀,+ má sì yẹ ìpinnu rẹ, torí pé ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí,*+ o ò sì gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀mí* pọ̀ mọ́ ẹran.