Ẹ́kísódù 29:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Kí o mú akọ màlúù náà wá síwájú àgọ́ ìpàdé, kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì gbé ọwọ́ wọn lé orí akọ màlúù náà.+ 11 Kí o pa akọ màlúù náà níwájú Jèhófà, lẹ́nu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.+
10 “Kí o mú akọ màlúù náà wá síwájú àgọ́ ìpàdé, kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì gbé ọwọ́ wọn lé orí akọ màlúù náà.+ 11 Kí o pa akọ màlúù náà níwájú Jèhófà, lẹ́nu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.+