-
Léfítíkù 20:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá arábìnrin ìyá rẹ tàbí arábìnrin bàbá rẹ lò pọ̀, torí ìyẹn máa dójú ti mọ̀lẹ́bí rẹ tó sún mọ́ ọ.+ Kí wọ́n jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn.
-