Jẹ́nẹ́sísì 30:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ló bá sọ fún un pé: “Ṣé ohun kékeré lo rò pé o ṣe nígbà tó o gba ọkọ mi?+ Ṣé o tún fẹ́ gba máńdírékì ọmọ mi ni?” Ni Réṣẹ́lì bá sọ pé: “Kò burú. Màá jẹ́ kó sùn tì ọ́ lálẹ́ òní tí o bá fún mi ní máńdírékì ọmọ rẹ.”
15 Ló bá sọ fún un pé: “Ṣé ohun kékeré lo rò pé o ṣe nígbà tó o gba ọkọ mi?+ Ṣé o tún fẹ́ gba máńdírékì ọmọ mi ni?” Ni Réṣẹ́lì bá sọ pé: “Kò burú. Màá jẹ́ kó sùn tì ọ́ lálẹ́ òní tí o bá fún mi ní máńdírékì ọmọ rẹ.”