- 
	                        
            
            Léfítíkù 16:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        19 Kó tún fi ìka rẹ̀ wọ́n lára ẹ̀jẹ̀ náà sára pẹpẹ lẹ́ẹ̀méje, kó lè wẹ̀ ẹ́ mọ́, kó sì sọ ọ́ di mímọ́ kúrò nínú ìwà àìmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. 
 
-