Òwe 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ẹni tó ń bo ìkórìíra rẹ̀ mọ́ra ń parọ́,+Ẹni tó sì ń tan ọ̀rọ̀ ìbàjẹ́* ká jẹ́ òmùgọ̀. 1 Jòhánù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹni tó bá sọ pé òun wà nínú ìmọ́lẹ̀, síbẹ̀ tó kórìíra+ arákùnrin rẹ̀, inú òkùnkùn ló ṣì wà.+ 1 Jòhánù 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Gbogbo ẹni tó bá kórìíra arákùnrin rẹ̀ jẹ́ apààyàn,+ ẹ sì mọ̀ pé kò sí apààyàn kankan tí ìyè àìnípẹ̀kun ṣì wà nínú rẹ̀.+
15 Gbogbo ẹni tó bá kórìíra arákùnrin rẹ̀ jẹ́ apààyàn,+ ẹ sì mọ̀ pé kò sí apààyàn kankan tí ìyè àìnípẹ̀kun ṣì wà nínú rẹ̀.+