Ẹ́kísódù 23:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “O ò gbọ́dọ̀ ni àjèjì lára. Ẹ mọ bó ṣe máa ń rí kéèyàn jẹ́ àjèjì,* torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+
9 “O ò gbọ́dọ̀ ni àjèjì lára. Ẹ mọ bó ṣe máa ń rí kéèyàn jẹ́ àjèjì,* torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+