Léfítíkù 18:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 “‘Ọkùnrin ò gbọ́dọ̀ bá ẹranko lò pọ̀, kó má bàa di aláìmọ̀; obìnrin ò sì gbọ́dọ̀ jẹ́ kí ẹranko bá òun lò pọ̀.+ Kì í ṣe ìwà tó tọ́.
23 “‘Ọkùnrin ò gbọ́dọ̀ bá ẹranko lò pọ̀, kó má bàa di aláìmọ̀; obìnrin ò sì gbọ́dọ̀ jẹ́ kí ẹranko bá òun lò pọ̀.+ Kì í ṣe ìwà tó tọ́.