-
Ẹ́kísódù 21:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “Àwọn ìdájọ́ tí wàá jẹ́ kí wọ́n mọ̀ nípa rẹ̀ nìyí:+
-
-
Diutarónómì 5:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Mósè wá pe gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì jọ, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, ẹ gbọ́ àwọn ìlànà àti àwọn ìdájọ́ tí mò ń kéde fún yín lónìí, kí ẹ mọ̀ wọ́n, kí ẹ sì rí i pé ẹ̀ ń pa wọ́n mọ́.
-