Léfítíkù 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí wọ́n fi ìkankan nínú àwọn ọmọ rẹ rúbọ sí* Mólékì.+ O ò gbọ́dọ̀ tipa bẹ́ẹ̀ sọ orúkọ Ọlọ́run rẹ di aláìmọ́.+ Èmi ni Jèhófà. Léfítíkù 19:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ ò gbọ́dọ̀ fi orúkọ mi búra èké,+ kí ẹ má bàa sọ orúkọ Ọlọ́run yín di aláìmọ́. Èmi ni Jèhófà. Léfítíkù 22:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹ ò gbọ́dọ̀ sọ orúkọ mímọ́ mi di aláìmọ́,+ ṣe ni kí ẹ fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Èmi ni Jèhófà, ẹni tó ń sọ yín di mímọ́,+
21 “‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí wọ́n fi ìkankan nínú àwọn ọmọ rẹ rúbọ sí* Mólékì.+ O ò gbọ́dọ̀ tipa bẹ́ẹ̀ sọ orúkọ Ọlọ́run rẹ di aláìmọ́.+ Èmi ni Jèhófà.
32 Ẹ ò gbọ́dọ̀ sọ orúkọ mímọ́ mi di aláìmọ́,+ ṣe ni kí ẹ fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Èmi ni Jèhófà, ẹni tó ń sọ yín di mímọ́,+