-
Léfítíkù 10:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ẹ ò gbọ́dọ̀ jáde ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ẹ máa kú, torí òróró àfiyanni Jèhófà wà lórí yín.”+ Torí náà, wọ́n ṣe ohun tí Mósè sọ.
-