Nọ́ńbà 19:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kí àlùfáà wá mú igi kédárì, ewéko hísópù+ àti òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò, kó sì jù ú sínú iná tí wọ́n ti ń sun màlúù náà. 7 Kí àlùfáà wá fọ aṣọ rẹ̀, kó sì fi omi wẹ ara rẹ̀,* lẹ́yìn náà, ó lè wá sínú ibùdó; àmọ́ àlùfáà náà máa jẹ́ aláìmọ́ títí di alẹ́.
6 Kí àlùfáà wá mú igi kédárì, ewéko hísópù+ àti òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò, kó sì jù ú sínú iná tí wọ́n ti ń sun màlúù náà. 7 Kí àlùfáà wá fọ aṣọ rẹ̀, kó sì fi omi wẹ ara rẹ̀,* lẹ́yìn náà, ó lè wá sínú ibùdó; àmọ́ àlùfáà náà máa jẹ́ aláìmọ́ títí di alẹ́.