Ẹ́kísódù 12:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ní ọjọ́ kìíní, kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́, kí ẹ sì ṣe àpéjọ mímọ́ míì ní ọjọ́ keje. Ẹ má ṣe iṣẹ́ kankan ní àwọn ọjọ́ yìí.+ Ohun tí ẹnì* kọ̀ọ̀kan máa jẹ nìkan ni kí wọ́n sè.
16 Ní ọjọ́ kìíní, kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́, kí ẹ sì ṣe àpéjọ mímọ́ míì ní ọjọ́ keje. Ẹ má ṣe iṣẹ́ kankan ní àwọn ọjọ́ yìí.+ Ohun tí ẹnì* kọ̀ọ̀kan máa jẹ nìkan ni kí wọ́n sè.