Ẹ́kísódù 23:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Bákan náà, kí ẹ máa ṣe Àjọyọ̀ Ìkórè* àwọn èso oko yín tó kọ́kọ́ pọ́n, èyí tí ẹ ṣiṣẹ́ kára láti gbìn;+ àti Àjọyọ̀ Ìkórèwọlé* níparí ọdún, nígbà tí ẹ bá kórè gbogbo ohun tí ẹ gbìn sí oko.+ Ẹ́kísódù 34:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Kí ẹ fi àwọn èso yín tó kọ́kọ́ pọ́n nígbà ìkórè àlìkámà* ṣe Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ àti Àjọyọ̀ Ìkórèwọlé* nígbà tí ọdún bá yí po.+
16 Bákan náà, kí ẹ máa ṣe Àjọyọ̀ Ìkórè* àwọn èso oko yín tó kọ́kọ́ pọ́n, èyí tí ẹ ṣiṣẹ́ kára láti gbìn;+ àti Àjọyọ̀ Ìkórèwọlé* níparí ọdún, nígbà tí ẹ bá kórè gbogbo ohun tí ẹ gbìn sí oko.+
22 “Kí ẹ fi àwọn èso yín tó kọ́kọ́ pọ́n nígbà ìkórè àlìkámà* ṣe Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ àti Àjọyọ̀ Ìkórèwọlé* nígbà tí ọdún bá yí po.+