Nọ́ńbà 28:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “‘Ní ọjọ́ àkọ́pọ́n èso,+ tí ẹ bá mú ọrẹ ọkà tuntun wá fún Jèhófà,+ kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́ nígbà tí ẹ bá ń ṣe àsè àwọn ọ̀sẹ̀.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára+ kankan. Nọ́ńbà 29:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “‘Kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́+ ní ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí, kí ẹ sì pọ́n ara yín* lójú. Ẹ kò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan.+
26 “‘Ní ọjọ́ àkọ́pọ́n èso,+ tí ẹ bá mú ọrẹ ọkà tuntun wá fún Jèhófà,+ kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́ nígbà tí ẹ bá ń ṣe àsè àwọn ọ̀sẹ̀.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára+ kankan.
7 “‘Kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́+ ní ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí, kí ẹ sì pọ́n ara yín* lójú. Ẹ kò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan.+