- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 18:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        15 Mósè sọ fún bàbá ìyàwó rẹ̀ pé: “Torí pé àwọn èèyàn ń wá sọ́dọ̀ mi kí n lè bá wọn wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ Ọlọ́run ni. 16 Tí ẹjọ́ kan bá délẹ̀, wọ́n á gbé e wá sọ́dọ̀ mi, màá sì ṣèdájọ́ ẹnì kìíní àti ẹnì kejì, màá jẹ́ kí wọ́n mọ àwọn ìpinnu Ọlọ́run tòótọ́ àti àwọn òfin rẹ̀.”+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 15:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        34 Wọ́n sì fi sínú àhámọ́,+ torí òfin ò tíì sọ ohun tí wọ́n máa ṣe fún un. 
 
-