Ẹ́kísódù 22:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Tí ẹnì kan bá jí akọ màlúù tàbí àgùntàn, tó sì pa á tàbí tó tà á, kó fi akọ màlúù márùn-ún dípò akọ màlúù náà, kó sì fi àgùntàn mẹ́rin dípò àgùntàn náà.+
22 “Tí ẹnì kan bá jí akọ màlúù tàbí àgùntàn, tó sì pa á tàbí tó tà á, kó fi akọ màlúù márùn-ún dípò akọ màlúù náà, kó sì fi àgùntàn mẹ́rin dípò àgùntàn náà.+