1 Kíróníkà 29:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nítorí àjèjì àti àlejò ni a jẹ́ níwájú rẹ, bí gbogbo àwọn baba ńlá wa ti jẹ́.+ Nítorí àwọn ọjọ́ wa lórí ilẹ̀ ayé da bí òjìji,+ kò sí ìrètí kankan.
15 Nítorí àjèjì àti àlejò ni a jẹ́ níwájú rẹ, bí gbogbo àwọn baba ńlá wa ti jẹ́.+ Nítorí àwọn ọjọ́ wa lórí ilẹ̀ ayé da bí òjìji,+ kò sí ìrètí kankan.