-
Diutarónómì 15:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Má kà á sí ìnira tí o bá dá a sílẹ̀, tó sì kúrò lọ́dọ̀ rẹ, torí pé ìlọ́po méjì iṣẹ́ tí alágbàṣe máa ṣe fún ọ ló ṣe ní ọdún mẹ́fà tó fi sìn ọ́, Jèhófà Ọlọ́run rẹ sì ti bù kún ọ nínú gbogbo ohun tí o ṣe.
-