Diutarónómì 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘O ò gbọ́dọ̀ gbẹ́ ère kankan fún ara rẹ+ tàbí kí o ṣe ohun* kan tó dà bí ohunkóhun lókè ọ̀run tàbí ní ayé tàbí nínú omi nísàlẹ̀.
8 “‘O ò gbọ́dọ̀ gbẹ́ ère kankan fún ara rẹ+ tàbí kí o ṣe ohun* kan tó dà bí ohunkóhun lókè ọ̀run tàbí ní ayé tàbí nínú omi nísàlẹ̀.