-
Dáníẹ́lì 3:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Àmọ́ tí kò bá tiẹ̀ gbà wá, a fẹ́ kí ìwọ ọba mọ̀ pé a ò ní sin àwọn ọlọ́run rẹ, a ò sì ní jọ́sìn ère wúrà tí o gbé kalẹ̀.”+
-
-
1 Kọ́ríńtì 10:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ sá fún ìbọ̀rìṣà.+
-