Míkà 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kálukú wọn máa jókòó* lábẹ́ àjàrà rẹ̀ àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀,+Ẹnì kankan ò sì ní dẹ́rù bà wọ́n,+Torí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló fi ẹnu ara rẹ̀ sọ ọ́.
4 Kálukú wọn máa jókòó* lábẹ́ àjàrà rẹ̀ àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀,+Ẹnì kankan ò sì ní dẹ́rù bà wọ́n,+Torí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló fi ẹnu ara rẹ̀ sọ ọ́.