Ìsíkíẹ́lì 5:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá fi ìyàn kọ lù yín, màá rán àwọn ẹranko burúkú sí yín,+ wọ́n á sì pa yín lọ́mọ jẹ. Àjàkálẹ̀ àrùn máa bò yín, ìtàjẹ̀sílẹ̀ á kún ilẹ̀ yín, màá sì fi idà kọ lù yín.+ Èmi, Jèhófà, ti sọ ọ́.’”
17 Màá fi ìyàn kọ lù yín, màá rán àwọn ẹranko burúkú sí yín,+ wọ́n á sì pa yín lọ́mọ jẹ. Àjàkálẹ̀ àrùn máa bò yín, ìtàjẹ̀sílẹ̀ á kún ilẹ̀ yín, màá sì fi idà kọ lù yín.+ Èmi, Jèhófà, ti sọ ọ́.’”