Ìsíkíẹ́lì 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Màá fi ìyàn kọ lù wọ́n, ó máa pa wọ́n run bí ìgbà tí mo bá ta wọ́n ní ọfà olóró. Ọfà tí mo bá ta yóò run yín.+ Màá mú kí ìyàn náà le sí i torí pé màá dáwọ́ oúnjẹ yín dúró.*+
16 “‘Màá fi ìyàn kọ lù wọ́n, ó máa pa wọ́n run bí ìgbà tí mo bá ta wọ́n ní ọfà olóró. Ọfà tí mo bá ta yóò run yín.+ Màá mú kí ìyàn náà le sí i torí pé màá dáwọ́ oúnjẹ yín dúró.*+