- 
	                        
            
            Àìsáyà 9:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        20 Ẹnì kan máa gé nǹkan lulẹ̀ ní ọwọ́ ọ̀tún, Àmọ́ ebi á ṣì máa pa á; Ẹnì kan sì máa jẹun ní ọwọ́ òsì, Àmọ́ kò ní yó. Kálukú máa jẹ ẹran apá rẹ̀, - 
	                        
            
            Míkà 6:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 Wàá jẹun àmọ́ o ò ní yó, Inú rẹ máa ṣófo.+ Tí o bá tiẹ̀ rí nǹkan kó, o ò ní lè kó o lọ, Tí o bá sì rí i kó lọ, màá fi í fún idà. 
 
- 
                                        
 
- 
	                        
            
            
 
-