Òwe 29:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ẹni tó ń bá olè kẹ́gbẹ́ kórìíra ara rẹ̀.* Ó lè gbọ́ pé kí àwọn èèyàn wá jẹ́rìí,* àmọ́ kò ní sọ nǹkan kan.+
24 Ẹni tó ń bá olè kẹ́gbẹ́ kórìíra ara rẹ̀.* Ó lè gbọ́ pé kí àwọn èèyàn wá jẹ́rìí,* àmọ́ kò ní sọ nǹkan kan.+