Sekaráyà 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mo sì fi ìjì tú wọn ká sí gbogbo orílẹ̀-èdè tí wọn ò mọ̀.+ Ilẹ̀ náà di ahoro lẹ́yìn wọn, ẹnì kankan ò kọjá níbẹ̀, ẹnì kankan ò sì pa dà síbẹ̀;+ torí wọ́n ti sọ ilẹ̀ dáradára náà di ohun tó ń dẹ́rù bani.’”
14 Mo sì fi ìjì tú wọn ká sí gbogbo orílẹ̀-èdè tí wọn ò mọ̀.+ Ilẹ̀ náà di ahoro lẹ́yìn wọn, ẹnì kankan ò kọjá níbẹ̀, ẹnì kankan ò sì pa dà síbẹ̀;+ torí wọ́n ti sọ ilẹ̀ dáradára náà di ohun tó ń dẹ́rù bani.’”