-
Nọ́ńbà 21:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ísírẹ́lì wá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Jèhófà pé: “Tí o bá fi àwọn èèyàn yìí lé mi lọ́wọ́, ó dájú pé màá run àwọn ìlú wọn pátápátá.”