ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 1:15-17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Kí àlùfáà sì mú un wá síbi pẹpẹ, kó já ọrùn rẹ̀ láìjá a tán, kó sì mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ, àmọ́ kó ro ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sí ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ. 16 Kó yọ àpò oúnjẹ ẹyẹ náà, kó tu àwọn ìyẹ́ rẹ̀, kó sì jù wọ́n sẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ lápá ìlà oòrùn, níbi tí eérú*+ wà. 17 Kó là á níbi àwọn ìyẹ́ rẹ̀ láìgé e sí méjì. Lẹ́yìn náà, kí àlùfáà mú kó rú èéfín lórí igi tó wà lórí iná lórí pẹpẹ. Ẹbọ sísun ni, ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, tó ní òórùn dídùn.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́