- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 1:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        33 iye àwọn tí wọ́n sì forúkọ wọn sílẹ̀ nínú ẹ̀yà Éfúrémù jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogójì ó lé ọgọ́rùn-ún márùn-ún (40,500). 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jóṣúà 17:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        17 Jóṣúà wá sọ fún ilé Jósẹ́fù, ó sọ fún Éfúrémù àti Mánásè pé: “Èèyàn púpọ̀ ni yín, ẹ sì lágbára gan-an. Kì í ṣe ilẹ̀ kan péré la máa fi kèké pín fún yín,+ 
 
-