- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 6:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        19 Àwọn ọmọ Mérárì ni Máhílì àti Múṣì. Ìdílé àwọn ọmọ Léfì nìyí, gẹ́gẹ́ bí ìlà ìdílé wọn.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 3:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        33 Látọ̀dọ̀ Mérárì ni ìdílé àwọn ọmọ Máhílì àti ìdílé àwọn ọmọ Múṣì ti ṣẹ̀ wá. Ìwọ̀nyí ni àwọn ìdílé Mérárì.+ 
 
-