Nọ́ńbà 26:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ó ṣẹlẹ̀ pé, Sélóféhádì ọmọ Héfà kò bímọ ọkùnrin, obìnrin+ nìkan ló bí, orúkọ àwọn ọmọbìnrin Sélóféhádì+ ni Málà, Nóà, Hógílà, Mílíkà àti Tírísà.
33 Ó ṣẹlẹ̀ pé, Sélóféhádì ọmọ Héfà kò bímọ ọkùnrin, obìnrin+ nìkan ló bí, orúkọ àwọn ọmọbìnrin Sélóféhádì+ ni Málà, Nóà, Hógílà, Mílíkà àti Tírísà.